Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 20 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿وَقَالُواْ لَوۡ شَآءَ ٱلرَّحۡمَٰنُ مَا عَبَدۡنَٰهُمۗ مَّا لَهُم بِذَٰلِكَ مِنۡ عِلۡمٍۖ إِنۡ هُمۡ إِلَّا يَخۡرُصُونَ ﴾
[الزُّخرُف: 20]
﴿وقالوا لو شاء الرحمن ما عبدناهم ما لهم بذلك من علم إن﴾ [الزُّخرُف: 20]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n tún wí pé: "Tí Àjọkẹ́-ayé bá fẹ́, àwa ìbá tí jọ́sìn fún wọn." Kò sí ìmọ̀ kan fún wọn nípa ìyẹn. Wọn kò sì jẹ́ kiní kan bí kò ṣe pé wọ́n ń parọ́ |