Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 25 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿فَٱنتَقَمۡنَا مِنۡهُمۡۖ فَٱنظُرۡ كَيۡفَ كَانَ عَٰقِبَةُ ٱلۡمُكَذِّبِينَ ﴾
[الزُّخرُف: 25]
﴿فانتقمنا منهم فانظر كيف كان عاقبة المكذبين﴾ [الزُّخرُف: 25]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, A gbẹ̀san lára wọn. Wo bí ìkángun àwọn olùpe-òdodo-nírọ́ ti rí |