Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 28 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿وَجَعَلَهَا كَلِمَةَۢ بَاقِيَةٗ فِي عَقِبِهِۦ لَعَلَّهُمۡ يَرۡجِعُونَ ﴾
[الزُّخرُف: 28]
﴿وجعلها كلمة باقية في عقبه لعلهم يرجعون﴾ [الزُّخرُف: 28]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Allāhu sì ṣe é ní ọ̀rọ̀ kan t’ó máa wà títí láéláé láààrin àwọn àrọ́mọdọ́mọ rẹ̀ nítorí kí wọ́n lè ṣẹ́rí padà (síbi òdodo) |