Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 27 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿إِلَّا ٱلَّذِي فَطَرَنِي فَإِنَّهُۥ سَيَهۡدِينِ ﴾
[الزُّخرُف: 27]
﴿إلا الذي فطرني فإنه سيهدين﴾ [الزُّخرُف: 27]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àfi Ẹni tí Ó ṣẹ̀dá mi. Dájúdájú Òun l’Ó máa fi ọ̀nà tààrà mọ̀ mí |