Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 31 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿وَقَالُواْ لَوۡلَا نُزِّلَ هَٰذَا ٱلۡقُرۡءَانُ عَلَىٰ رَجُلٖ مِّنَ ٱلۡقَرۡيَتَيۡنِ عَظِيمٍ ﴾
[الزُّخرُف: 31]
﴿وقالوا لولا نـزل هذا القرآن على رجل من القريتين عظيم﴾ [الزُّخرُف: 31]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n tún wí pé: "Kí ni kò jẹ́ kí Wọ́n sọ al-Ƙur’ān yìí kalẹ̀ fún ọkùnrin pàtàkì kan nínú àwọn ìlú méjèèjì |