Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 30 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿وَلَمَّا جَآءَهُمُ ٱلۡحَقُّ قَالُواْ هَٰذَا سِحۡرٞ وَإِنَّا بِهِۦ كَٰفِرُونَ ﴾
[الزُّخرُف: 30]
﴿ولما جاءهم الحق قالوا هذا سحر وإنا به كافرون﴾ [الزُّخرُف: 30]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí òdodo dé bá wọn, wọ́n wí pé: "Idán ni èyí; dájúdájú àwa kò sì níí gbà á gbọ́ |