Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 37 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿وَإِنَّهُمۡ لَيَصُدُّونَهُمۡ عَنِ ٱلسَّبِيلِ وَيَحۡسَبُونَ أَنَّهُم مُّهۡتَدُونَ ﴾
[الزُّخرُف: 37]
﴿وإنهم ليصدونهم عن السبيل ويحسبون أنهم مهتدون﴾ [الزُّخرُف: 37]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn èṣù náà yóò máa ṣẹ́rí wọn kúrò lójú ọ̀nà (ẹ̀sìn Allāhu). Wọn yó sì máa lérò pé dájúdájú àwọn ni olùmọ̀nà |