Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 50 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿فَلَمَّا كَشَفۡنَا عَنۡهُمُ ٱلۡعَذَابَ إِذَا هُمۡ يَنكُثُونَ ﴾ 
[الزُّخرُف: 50]
﴿فلما كشفنا عنهم العذاب إذا هم ينكثون﴾ [الزُّخرُف: 50]
| Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣùgbọ́n nígbà tí A mú ìyà kúrò fún wọn, nígbà náà ni wọ́n tún ń yẹ àdéhùn  |