Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 52 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿أَمۡ أَنَا۠ خَيۡرٞ مِّنۡ هَٰذَا ٱلَّذِي هُوَ مَهِينٞ وَلَا يَكَادُ يُبِينُ ﴾
[الزُّخرُف: 52]
﴿أم أنا خير من هذا الذي هو مهين ولا يكاد يبين﴾ [الزُّخرُف: 52]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tàbí ṣé èmi kò lóore jùlọ sí èyí tí ó jẹ́ ọ̀lẹ yẹpẹrẹ, tí ó fẹ́ẹ̀ má lè dá ọ̀rọ̀ sọ yanjú |