Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 61 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿وَإِنَّهُۥ لَعِلۡمٞ لِّلسَّاعَةِ فَلَا تَمۡتَرُنَّ بِهَا وَٱتَّبِعُونِۚ هَٰذَا صِرَٰطٞ مُّسۡتَقِيمٞ ﴾
[الزُّخرُف: 61]
﴿وإنه لعلم للساعة فلا تمترن بها واتبعون هذا صراط مستقيم﴾ [الزُّخرُف: 61]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú òun ni ìmọ̀ (tàbí àmì fún ìsúnmọ́) Àkókò náà. Nítorí náà, ẹ ò gbọdọ̀ ṣeyèméjì nípa rẹ̀. Kí ẹ sì tẹ̀lé mi. Èyí ni ọ̀nà tààrà |