Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 70 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿ٱدۡخُلُواْ ٱلۡجَنَّةَ أَنتُمۡ وَأَزۡوَٰجُكُمۡ تُحۡبَرُونَ ﴾
[الزُّخرُف: 70]
﴿ادخلوا الجنة أنتم وأزواجكم تحبرون﴾ [الزُّخرُف: 70]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ wọ inú Ọgbà Ìdẹ̀ra, ẹ̀yin àti àwọn ìyàwó yín; kí ẹ máa dunnú |