Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 69 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ بِـَٔايَٰتِنَا وَكَانُواْ مُسۡلِمِينَ ﴾
[الزُّخرُف: 69]
﴿الذين آمنوا بآياتنا وكانوا مسلمين﴾ [الزُّخرُف: 69]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Àwọn ni) àwọn t’ó gbàgbọ́ nínú àwọn āyah Wa, tí wọ́n sì jẹ́ mùsùlùmí (olùjuwọ́-jusẹ̀ sílẹ̀ fún Allāhu) |