Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 8 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿فَأَهۡلَكۡنَآ أَشَدَّ مِنۡهُم بَطۡشٗا وَمَضَىٰ مَثَلُ ٱلۡأَوَّلِينَ ﴾
[الزُّخرُف: 8]
﴿فأهلكنا أشد منهم بطشا ومضى مثل الأولين﴾ [الزُّخرُف: 8]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, A ti pa àwọn t’ó ní agbára ju àwọn (wọ̀nyí) rẹ́. Àpèjúwe (ìparun) àwọn ẹni àkọ́kọ́ sì ti ṣíwájú |