Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 89 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿فَٱصۡفَحۡ عَنۡهُمۡ وَقُلۡ سَلَٰمٞۚ فَسَوۡفَ يَعۡلَمُونَ ﴾
[الزُّخرُف: 89]
﴿فاصفح عنهم وقل سلام فسوف يعلمون﴾ [الزُّخرُف: 89]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ṣàmójú kúrò fún wọn, kí ó sì sọ pé: "Àlàáfíà!" Láìpẹ́ wọ́n máa mọ̀ |