Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 10 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿فَٱرۡتَقِبۡ يَوۡمَ تَأۡتِي ٱلسَّمَآءُ بِدُخَانٖ مُّبِينٖ ﴾
[الدُّخان: 10]
﴿فارتقب يوم تأتي السماء بدخان مبين﴾ [الدُّخان: 10]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, máa retí ọjọ́ tí sánmọ̀ yóò mú èéfín pọ́nńbélé wá |