Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 31 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿مِن فِرۡعَوۡنَۚ إِنَّهُۥ كَانَ عَالِيٗا مِّنَ ٱلۡمُسۡرِفِينَ ﴾
[الدُّخان: 31]
﴿من فرعون إنه كان عاليا من المسرفين﴾ [الدُّخان: 31]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (A là wọ́n) lọ́wọ́ Fir‘aon. Dájúdájú ó jẹ́ onígbèéraga. Ó sì wà nínú àwọn alákọyọ |