Quran with Yoruba translation - Surah Muhammad ayat 24 - مُحمد - Page - Juz 26
﴿أَفَلَا يَتَدَبَّرُونَ ٱلۡقُرۡءَانَ أَمۡ عَلَىٰ قُلُوبٍ أَقۡفَالُهَآ ﴾
[مُحمد: 24]
﴿أفلا يتدبرون القرآن أم على قلوب أقفالها﴾ [مُحمد: 24]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé wọn kò níí ronú nípa al-Ƙur’ān ni tàbí àwọn àgádágodo ti wà lórí ọkàn wọn ni |