×

Dajudaju awon t’o n sadehun fun o (pe awon ko nii fese 48:10 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Fath ⮕ (48:10) ayat 10 in Yoruba

48:10 Surah Al-Fath ayat 10 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Fath ayat 10 - الفَتح - Page - Juz 26

﴿إِنَّ ٱلَّذِينَ يُبَايِعُونَكَ إِنَّمَا يُبَايِعُونَ ٱللَّهَ يَدُ ٱللَّهِ فَوۡقَ أَيۡدِيهِمۡۚ فَمَن نَّكَثَ فَإِنَّمَا يَنكُثُ عَلَىٰ نَفۡسِهِۦۖ وَمَنۡ أَوۡفَىٰ بِمَا عَٰهَدَ عَلَيۡهُ ٱللَّهَ فَسَيُؤۡتِيهِ أَجۡرًا عَظِيمٗا ﴾
[الفَتح: 10]

Dajudaju awon t’o n sadehun fun o (pe awon ko nii fese fee loju ogun), dajudaju Allahu ni won n sadehun fun. Owo Allahu wa loke owo won. Enikeni ti o ba tu adehun re, o tu u fun emi ara re. Enikeni ti o ba si mu adehun t’o se fun Allahu se, (Allahu) yoo fun un ni esan nla

❮ Previous Next ❯

ترجمة: إن الذين يبايعونك إنما يبايعون الله يد الله فوق أيديهم فمن نكث, باللغة اليوربا

﴿إن الذين يبايعونك إنما يبايعون الله يد الله فوق أيديهم فمن نكث﴾ [الفَتح: 10]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Dájúdájú àwọn t’ó ń ṣàdéhùn fún ọ (pé àwọn kò níí fẹsẹ̀ fẹ́ẹ lójú ogun), dájúdájú Allāhu ni wọ́n ń ṣàdéhùn fún. Ọwọ́ Allāhu wà lókè ọwọ́ wọn. Ẹnikẹ́ni tí ó bá tú àdéhùn rẹ̀, ó tú u fún ẹ̀mí ara rẹ̀. Ẹnikẹ́ni tí ó bá sì mú àdéhùn t’ó ṣe fún Allāhu ṣẹ, (Allāhu) yóò fún un ní ẹ̀san ńlá
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek