Quran with Yoruba translation - Surah Al-hujurat ayat 8 - الحُجُرَات - Page - Juz 26
﴿فَضۡلٗا مِّنَ ٱللَّهِ وَنِعۡمَةٗۚ وَٱللَّهُ عَلِيمٌ حَكِيمٞ ﴾
[الحُجُرَات: 8]
﴿فضلا من الله ونعمة والله عليم حكيم﴾ [الحُجُرَات: 8]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Èyí jẹ́) oore àjùlọ àti ìdẹ̀ra láti ọ̀dọ̀ Allāhu. Allāhu sì ni Onímọ̀, Ọlọ́gbọ́n |