Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ma’idah ayat 21 - المَائدة - Page - Juz 6
﴿يَٰقَوۡمِ ٱدۡخُلُواْ ٱلۡأَرۡضَ ٱلۡمُقَدَّسَةَ ٱلَّتِي كَتَبَ ٱللَّهُ لَكُمۡ وَلَا تَرۡتَدُّواْ عَلَىٰٓ أَدۡبَارِكُمۡ فَتَنقَلِبُواْ خَٰسِرِينَ ﴾
[المَائدة: 21]
﴿ياقوم ادخلوا الأرض المقدسة التي كتب الله لكم ولا ترتدوا على أدباركم﴾ [المَائدة: 21]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ̀yin ìjọ mi, ẹ wọ orí ilẹ̀ mímọ́ tí Allāhu kọ mọ́ yín. Ẹ má se padà sẹ́yìn, nítorí kí ẹ má baà padà di ẹni òfò |