Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ma’idah ayat 30 - المَائدة - Page - Juz 6
﴿فَطَوَّعَتۡ لَهُۥ نَفۡسُهُۥ قَتۡلَ أَخِيهِ فَقَتَلَهُۥ فَأَصۡبَحَ مِنَ ٱلۡخَٰسِرِينَ ﴾
[المَائدة: 30]
﴿فطوعت له نفسه قتل أخيه فقتله فأصبح من الخاسرين﴾ [المَائدة: 30]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ̀mí rẹ̀ sì gbà fún un láti pa arákùnrin rẹ̀. Ó pa á. Ó sì di ọ̀kan nínú àwọn ẹni òfò |