Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 17 - قٓ - Page - Juz 26
﴿إِذۡ يَتَلَقَّى ٱلۡمُتَلَقِّيَانِ عَنِ ٱلۡيَمِينِ وَعَنِ ٱلشِّمَالِ قَعِيدٞ ﴾
[قٓ: 17]
﴿إذ يتلقى المتلقيان عن اليمين وعن الشمال قعيد﴾ [قٓ: 17]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Rántí) nígbà tí (mọlāika) àwọn agbọ̀rọ̀-sílẹ̀ méjì bá bẹ̀rẹ̀sí gba ọ̀rọ̀ (sílẹ̀), tí ọ̀kan jókòó sí ọ̀tún, tí ọ̀kan jókòó sí òsì |