Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 18 - قٓ - Page - Juz 26
﴿مَّا يَلۡفِظُ مِن قَوۡلٍ إِلَّا لَدَيۡهِ رَقِيبٌ عَتِيدٞ ﴾
[قٓ: 18]
﴿ما يلفظ من قول إلا لديه رقيب عتيد﴾ [قٓ: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ẹnì kan) kò sì níí sọ ọ̀rọ̀ kan àyàfi kí ẹ̀ṣọ́ kan wà pẹ̀lú rẹ̀ (fún àkọsílẹ̀ rẹ̀) |