Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 33 - قٓ - Page - Juz 26
﴿مَّنۡ خَشِيَ ٱلرَّحۡمَٰنَ بِٱلۡغَيۡبِ وَجَآءَ بِقَلۡبٖ مُّنِيبٍ ﴾
[قٓ: 33]
﴿من خشي الرحمن بالغيب وجاء بقلب منيب﴾ [قٓ: 33]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹnikẹ́ni tí ó bá páyà Allāhu ní ìkọ̀kọ̀, tí ó tún dé pẹ̀lú ọkàn tó ṣẹ́rí padà sí ọ̀dọ̀ Allāhu (nípa ìronúpìwàdà) |