Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 32 - قٓ - Page - Juz 26
﴿هَٰذَا مَا تُوعَدُونَ لِكُلِّ أَوَّابٍ حَفِيظٖ ﴾
[قٓ: 32]
﴿هذا ما توعدون لكل أواب حفيظ﴾ [قٓ: 32]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Èyí ni ohun tí À ń ṣe ní àdéhùn fún gbogbo olùronúpìwàdà, olùṣọ́ (òfin Allāhu) |