Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 43 - قٓ - Page - Juz 26
﴿إِنَّا نَحۡنُ نُحۡيِۦ وَنُمِيتُ وَإِلَيۡنَا ٱلۡمَصِيرُ ﴾
[قٓ: 43]
﴿إنا نحن نحيي ونميت وإلينا المصير﴾ [قٓ: 43]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Àwa, Àwa l’À ń sọ ẹ̀dá di alààyè. A sì ń sọ ọ́ di òkú. Ọ̀dọ̀ Wa sì ni àbọ̀ ẹ̀dá |