Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 44 - الذَّاريَات - Page - Juz 27
﴿فَعَتَوۡاْ عَنۡ أَمۡرِ رَبِّهِمۡ فَأَخَذَتۡهُمُ ٱلصَّٰعِقَةُ وَهُمۡ يَنظُرُونَ ﴾
[الذَّاريَات: 44]
﴿فعتوا عن أمر ربهم فأخذتهم الصاعقة وهم ينظرون﴾ [الذَّاريَات: 44]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n ṣègbéraga sí àṣẹ Olúwa wọn. Nítorí náà, igbe ìparun mú wọ́n; wọ́n sì ń wò bọ̀ọ̀ |