Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 57 - الذَّاريَات - Page - Juz 27
﴿مَآ أُرِيدُ مِنۡهُم مِّن رِّزۡقٖ وَمَآ أُرِيدُ أَن يُطۡعِمُونِ ﴾
[الذَّاريَات: 57]
﴿ما أريد منهم من رزق وما أريد أن يطعمون﴾ [الذَّاريَات: 57]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Èmi kò gbèrò arísìkí kan láti ọ̀dọ̀ wọn. Èmi kò sì gbèrò pé kí wọ́n máa bọ́ Mi |