Quran with Yoruba translation - Surah AT-Tur ayat 20 - الطُّور - Page - Juz 27
﴿مُتَّكِـِٔينَ عَلَىٰ سُرُرٖ مَّصۡفُوفَةٖۖ وَزَوَّجۡنَٰهُم بِحُورٍ عِينٖ ﴾
[الطُّور: 20]
﴿متكئين على سرر مصفوفة وزوجناهم بحور عين﴾ [الطُّور: 20]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn yóò rọ̀gbọ̀kú sórí àwọn ibùsùn tí wọ́n tò ní ọ̀wọ̀ọ̀wọ́. A sì máa fún wọn ní àwọn ìyàwó ẹlẹ́yinjú ẹgẹ́ |