Quran with Yoruba translation - Surah AT-Tur ayat 33 - الطُّور - Page - Juz 27
﴿أَمۡ يَقُولُونَ تَقَوَّلَهُۥۚ بَل لَّا يُؤۡمِنُونَ ﴾
[الطُّور: 33]
﴿أم يقولون تقوله بل لا يؤمنون﴾ [الطُّور: 33]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tàbí wọ́n ń wí pé: "Ó dá (al-Ƙur’ān) hun fúnra rẹ̀ ni." Rárá o, wọn kò gbàgbọ́ ni |