Quran with Yoruba translation - Surah An-Najm ayat 35 - النَّجم - Page - Juz 27
﴿أَعِندَهُۥ عِلۡمُ ٱلۡغَيۡبِ فَهُوَ يَرَىٰٓ ﴾ 
[النَّجم: 35]
﴿أعنده علم الغيب فهو يرى﴾ [النَّجم: 35]
| Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé ìmọ̀ ìkọ̀kọ̀ wà ní ọ̀dọ̀ rẹ, tí ó sì ń rí i (pé ẹlòmíìràn l’ó ma bá òun jìyà lọ́run)  |