Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qamar ayat 50 - القَمَر - Page - Juz 27
﴿وَمَآ أَمۡرُنَآ إِلَّا وَٰحِدَةٞ كَلَمۡحِۭ بِٱلۡبَصَرِ ﴾
[القَمَر: 50]
﴿وما أمرنا إلا واحدة كلمح بالبصر﴾ [القَمَر: 50]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àṣẹ Wa (fún mímú n̄ǹkan bẹ) kò tayọ (àṣẹ) ẹyọ kan ṣoṣo gẹ́gẹ́ bí ìṣẹ́jú |