Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qamar ayat 8 - القَمَر - Page - Juz 27
﴿مُّهۡطِعِينَ إِلَى ٱلدَّاعِۖ يَقُولُ ٱلۡكَٰفِرُونَ هَٰذَا يَوۡمٌ عَسِرٞ ﴾
[القَمَر: 8]
﴿مهطعين إلى الداع يقول الكافرون هذا يوم عسر﴾ [القَمَر: 8]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn yó sì máa yára lọ sí ọ̀dọ̀ olùpèpè náà. Àwọn aláìgbàgbọ́ yó sì wí pé: "Èyí ni ọjọ́ ìṣòro |