Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Rahman ayat 14 - الرَّحمٰن - Page - Juz 27
﴿خَلَقَ ٱلۡإِنسَٰنَ مِن صَلۡصَٰلٖ كَٱلۡفَخَّارِ ﴾
[الرَّحمٰن: 14]
﴿خلق الإنسان من صلصال كالفخار﴾ [الرَّحمٰن: 14]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Allāhu) ṣẹ̀dá ènìyàn láti ara amọ̀ gbígbẹ t’ó ń dún kokoko bí ìkòkò amọ̀ |