Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Rahman ayat 76 - الرَّحمٰن - Page - Juz 27
﴿مُتَّكِـِٔينَ عَلَىٰ رَفۡرَفٍ خُضۡرٖ وَعَبۡقَرِيٍّ حِسَانٖ ﴾
[الرَّحمٰن: 76]
﴿متكئين على رفرف خضر وعبقري حسان﴾ [الرَّحمٰن: 76]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn yóò rọ̀gbọ̀kú lórí àwọn tìmùtìmù aláwọ̀ ewéko àti ìtẹ́ t’ó dára |