Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Rahman ayat 9 - الرَّحمٰن - Page - Juz 27
﴿وَأَقِيمُواْ ٱلۡوَزۡنَ بِٱلۡقِسۡطِ وَلَا تُخۡسِرُواْ ٱلۡمِيزَانَ ﴾
[الرَّحمٰن: 9]
﴿وأقيموا الوزن بالقسط ولا تخسروا الميزان﴾ [الرَّحمٰن: 9]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ gbé òṣùwọ̀n náà dúró pẹ̀lú dọ́gbadọ́gba. Kí ẹ sì má ṣe dín òṣùwọ̀n kù |