Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mujadilah ayat 14 - المُجَادلة - Page - Juz 28
﴿۞ أَلَمۡ تَرَ إِلَى ٱلَّذِينَ تَوَلَّوۡاْ قَوۡمًا غَضِبَ ٱللَّهُ عَلَيۡهِم مَّا هُم مِّنكُمۡ وَلَا مِنۡهُمۡ وَيَحۡلِفُونَ عَلَى ٱلۡكَذِبِ وَهُمۡ يَعۡلَمُونَ ﴾
[المُجَادلة: 14]
﴿ألم تر إلى الذين تولوا قوما غضب الله عليهم ما هم منكم﴾ [المُجَادلة: 14]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé o ò rí àwọn t’ó mú ìjọ kan tí Allāhu bínú sí ní ọ̀rẹ́? Wọn kì í ṣe ara yín, wọn kò sì jẹ́ ara wọn. Wọ́n yó sì máa búra lórí irọ́, wọ́n sì mọ̀ |