Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 134 - الأنعَام - Page - Juz 8
﴿إِنَّ مَا تُوعَدُونَ لَأٓتٖۖ وَمَآ أَنتُم بِمُعۡجِزِينَ ﴾
[الأنعَام: 134]
﴿إن ما توعدون لآت وما أنتم بمعجزين﴾ [الأنعَام: 134]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú ohun tí À ń ṣe ní àdéhùn fun yín, ó kúkú ń bọ̀ wá ṣẹlẹ̀; ẹ̀yin kò sì níí mórí bọ́ |