×

So pe: “Eyin eniyan mi, e duro sori ona yin, dajudaju emi 6:135 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-An‘am ⮕ (6:135) ayat 135 in Yoruba

6:135 Surah Al-An‘am ayat 135 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 135 - الأنعَام - Page - Juz 8

﴿قُلۡ يَٰقَوۡمِ ٱعۡمَلُواْ عَلَىٰ مَكَانَتِكُمۡ إِنِّي عَامِلٞۖ فَسَوۡفَ تَعۡلَمُونَ مَن تَكُونُ لَهُۥ عَٰقِبَةُ ٱلدَّارِۚ إِنَّهُۥ لَا يُفۡلِحُ ٱلظَّٰلِمُونَ ﴾
[الأنعَام: 135]

So pe: “Eyin eniyan mi, e duro sori ona yin, dajudaju emi naa yoo duro (sori ona mi), laipe e maa mo eni ti Ogba (Idera) yoo je ikangun tire. Dajudaju awon alabosi ko nii jere.”

❮ Previous Next ❯

ترجمة: قل ياقوم اعملوا على مكانتكم إني عامل فسوف تعلمون من تكون له, باللغة اليوربا

﴿قل ياقوم اعملوا على مكانتكم إني عامل فسوف تعلمون من تكون له﴾ [الأنعَام: 135]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Sọ pé: “Ẹ̀yin ènìyàn mi, ẹ dúró sórí ọ̀nà yín, dájúdájú èmi náà yóò dúró (sórí ọ̀nà mi), láìpẹ́ ẹ̀ máa mọ ẹni tí Ọgbà (Ìdẹ̀ra) yóò jẹ́ ìkángun tirẹ̀. Dájúdájú àwọn alábòsí kò níí jèrè.”
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek