×

Won tun wi pe: "Eewo ni awon eran-osin ati nnkan oko wonyi. 6:138 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-An‘am ⮕ (6:138) ayat 138 in Yoruba

6:138 Surah Al-An‘am ayat 138 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 138 - الأنعَام - Page - Juz 8

﴿وَقَالُواْ هَٰذِهِۦٓ أَنۡعَٰمٞ وَحَرۡثٌ حِجۡرٞ لَّا يَطۡعَمُهَآ إِلَّا مَن نَّشَآءُ بِزَعۡمِهِمۡ وَأَنۡعَٰمٌ حُرِّمَتۡ ظُهُورُهَا وَأَنۡعَٰمٞ لَّا يَذۡكُرُونَ ٱسۡمَ ٱللَّهِ عَلَيۡهَا ٱفۡتِرَآءً عَلَيۡهِۚ سَيَجۡزِيهِم بِمَا كَانُواْ يَفۡتَرُونَ ﴾
[الأنعَام: 138]

Won tun wi pe: "Eewo ni awon eran-osin ati nnkan oko wonyi. Eni kan ko gbodo je e afi eni ti a ba fe, pelu oro won lai ni eri lowo." - Awon eran-osin kan tun n be ti won se eyin won ni eewo (fun gigun ati eru riru), awon eran kan tun n be ti won ki i fi oruko Allahu pa. (Won fi awon nnkan wonyi) da adapa iro mo Allahu ni. O si maa san won ni esan ohun ti won n da ni adapa iro

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وقالوا هذه أنعام وحرث حجر لا يطعمها إلا من نشاء بزعمهم وأنعام, باللغة اليوربا

﴿وقالوا هذه أنعام وحرث حجر لا يطعمها إلا من نشاء بزعمهم وأنعام﴾ [الأنعَام: 138]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Wọ́n tún wí pé: "Èèwọ̀ ni àwọn ẹran-ọ̀sìn àti n̄ǹkan oko wọ̀nyí. Ẹnì kan kò gbọdọ̀ jẹ ẹ́ àfi ẹni tí a bá fẹ́, pẹ̀lú ọ̀rọ̀ wọn láì ní ẹ̀rí lọ́wọ́." - Àwọn ẹran-ọ̀sìn kan tún ń bẹ tí wọ́n ṣe ẹ̀yìn wọn ní èèwọ̀ (fún gígùn àti ẹrù rírù), àwọn ẹran kan tún ń bẹ tí wọn kì í fi orúkọ Allāhu pa. (Wọ́n fi àwọn n̄ǹkan wọ̀nyí) dá àdápa irọ́ mọ́ Allāhu ni. Ó sì máa san wọ́n ní ẹ̀san ohun tí wọ́n ń dá ní àdápa irọ́
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek