Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 15 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿قُلۡ إِنِّيٓ أَخَافُ إِنۡ عَصَيۡتُ رَبِّي عَذَابَ يَوۡمٍ عَظِيمٖ ﴾
[الأنعَام: 15]
﴿قل إني أخاف إن عصيت ربي عذاب يوم عظيم﴾ [الأنعَام: 15]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: “Dájúdájú èmi ń páyà ìyà Ọjọ́ Ńlá, tí mo bá fi lè yapa Olúwa mi.” |