Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 16 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿مَّن يُصۡرَفۡ عَنۡهُ يَوۡمَئِذٖ فَقَدۡ رَحِمَهُۥۚ وَذَٰلِكَ ٱلۡفَوۡزُ ٱلۡمُبِينُ ﴾
[الأنعَام: 16]
﴿من يصرف عنه يومئذ فقد رحمه وذلك الفوز المبين﴾ [الأنعَام: 16]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹnikẹ́ni tí A bá darí rẹ̀ kúrò níbi (ìyà) ní Ọjọ́ yẹn, (Allāhu) ti ṣàánú rẹ̀. Ìyẹn sì ni èrèǹjẹ pọ́nńbélé |