×

So pe: "Dajudaju iku ti e n sa fun, dajudaju o maa 62:8 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Jumu‘ah ⮕ (62:8) ayat 8 in Yoruba

62:8 Surah Al-Jumu‘ah ayat 8 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Jumu‘ah ayat 8 - الجُمعَة - Page - Juz 28

﴿قُلۡ إِنَّ ٱلۡمَوۡتَ ٱلَّذِي تَفِرُّونَ مِنۡهُ فَإِنَّهُۥ مُلَٰقِيكُمۡۖ ثُمَّ تُرَدُّونَ إِلَىٰ عَٰلِمِ ٱلۡغَيۡبِ وَٱلشَّهَٰدَةِ فَيُنَبِّئُكُم بِمَا كُنتُمۡ تَعۡمَلُونَ ﴾
[الجُمعَة: 8]

So pe: "Dajudaju iku ti e n sa fun, dajudaju o maa pade yin. Leyin naa, won yoo da yin pada si odo Onimo-ikoko ati gbangba. O si maa fun yin ni iro ohun ti e n se nise

❮ Previous Next ❯

ترجمة: قل إن الموت الذي تفرون منه فإنه ملاقيكم ثم تردون إلى عالم, باللغة اليوربا

﴿قل إن الموت الذي تفرون منه فإنه ملاقيكم ثم تردون إلى عالم﴾ [الجُمعَة: 8]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Sọ pé: "Dájúdájú ikú tí ẹ̀ ń sá fún, dájúdájú ó máa pàdé yín. Lẹ́yìn náà, wọn yóò da yín padà sí ọ̀dọ̀ Onímọ̀-ìkọ̀kọ̀ àti gban̄gba. Ó sì máa fun yín ní ìró ohun tí ẹ̀ ń ṣe níṣẹ́
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek