Quran with Yoruba translation - Surah Al-Jumu‘ah ayat 7 - الجُمعَة - Page - Juz 28
﴿وَلَا يَتَمَنَّوۡنَهُۥٓ أَبَدَۢا بِمَا قَدَّمَتۡ أَيۡدِيهِمۡۚ وَٱللَّهُ عَلِيمُۢ بِٱلظَّٰلِمِينَ ﴾
[الجُمعَة: 7]
﴿ولا يتمنونه أبدا بما قدمت أيديهم والله عليم بالظالمين﴾ [الجُمعَة: 7]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn kò níí tọrọ rẹ̀ láéláé nítorí ohun tí ọwọ́ wọn ti tì ṣíwájú. Allāhu sì ni Onímọ̀ nípa àwọn alábòsí |