Quran with Yoruba translation - Surah Al-Munafiqun ayat 11 - المُنَافِقُونَ - Page - Juz 28
﴿وَلَن يُؤَخِّرَ ٱللَّهُ نَفۡسًا إِذَا جَآءَ أَجَلُهَاۚ وَٱللَّهُ خَبِيرُۢ بِمَا تَعۡمَلُونَ ﴾
[المُنَافِقُونَ: 11]
﴿ولن يؤخر الله نفسا إذا جاء أجلها والله خبير بما تعملون﴾ [المُنَافِقُونَ: 11]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Allāhu kò sì níí lọ́ ẹ̀mí kan lára nígbà tí ọjọ́ ikú rẹ̀ bá dé. Allāhu sì ni Alámọ̀tán nípa ohun tí ẹ̀ ń ṣe níṣẹ́ |