Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mulk ayat 12 - المُلك - Page - Juz 29
﴿إِنَّ ٱلَّذِينَ يَخۡشَوۡنَ رَبَّهُم بِٱلۡغَيۡبِ لَهُم مَّغۡفِرَةٞ وَأَجۡرٞ كَبِيرٞ ﴾
[المُلك: 12]
﴿إن الذين يخشون ربهم بالغيب لهم مغفرة وأجر كبير﴾ [المُلك: 12]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn t’ó ń páyà Olúwa wọn ní ìkọ̀kọ̀, àforíjìn àti ẹ̀san t’ó tóbi ń bẹ fún wọn |