Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mulk ayat 11 - المُلك - Page - Juz 29
﴿فَٱعۡتَرَفُواْ بِذَنۢبِهِمۡ فَسُحۡقٗا لِّأَصۡحَٰبِ ٱلسَّعِيرِ ﴾
[المُلك: 11]
﴿فاعترفوا بذنبهم فسحقا لأصحاب السعير﴾ [المُلك: 11]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sì jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ wọn. Nítorí náà, ìjìnnà sí ìkẹ́ Allāhu yó wà fún àwọn èrò inú Iná t’ó ń jò fòfò |