Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mulk ayat 20 - المُلك - Page - Juz 29
﴿أَمَّنۡ هَٰذَا ٱلَّذِي هُوَ جُندٞ لَّكُمۡ يَنصُرُكُم مِّن دُونِ ٱلرَّحۡمَٰنِۚ إِنِ ٱلۡكَٰفِرُونَ إِلَّا فِي غُرُورٍ ﴾
[المُلك: 20]
﴿أمن هذا الذي هو جند لكم ينصركم من دون الرحمن إن الكافرون﴾ [المُلك: 20]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ta ni ẹni tí ó máa jẹ́ ọmọ ogun fun yín, tí ó máa ràn yín lọ́wọ́ lẹ́yìn Àjọkẹ́-ayé? (Nínú) kí ni àwọn aláìgbàgbọ́ wà bí kò ṣe nínú ẹ̀tàn |