Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mulk ayat 29 - المُلك - Page - Juz 29
﴿قُلۡ هُوَ ٱلرَّحۡمَٰنُ ءَامَنَّا بِهِۦ وَعَلَيۡهِ تَوَكَّلۡنَاۖ فَسَتَعۡلَمُونَ مَنۡ هُوَ فِي ضَلَٰلٖ مُّبِينٖ ﴾
[المُلك: 29]
﴿قل هو الرحمن آمنا به وعليه توكلنا فستعلمون من هو في ضلال﴾ [المُلك: 29]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: "Òun ni Àjọkẹ́-ayé. Àwa gbà Á gbọ́. Òun sì la gbáralé. Láìpẹ́ ẹ máa mọ ta ni ó wà nínú ìṣìnà pọ́nńbélé |