Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mulk ayat 4 - المُلك - Page - Juz 29
﴿ثُمَّ ٱرۡجِعِ ٱلۡبَصَرَ كَرَّتَيۡنِ يَنقَلِبۡ إِلَيۡكَ ٱلۡبَصَرُ خَاسِئٗا وَهُوَ حَسِيرٞ ﴾
[المُلك: 4]
﴿ثم ارجع البصر كرتين ينقلب إليك البصر خاسئا وهو حسير﴾ [المُلك: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, wò ó padà ní ẹ̀ẹ̀ mejì, kí ojú rẹ padà sí ọ̀dọ̀ rẹ pẹ̀lú ìyẹpẹrẹ. Ó sì máa káàárẹ̀ |